Post by Sunday Ajayi (@Areafather)
Wọ́n ń pa òwe yìí nígbà tí ẹnì kan bá ń dáná rògbòdìyàn tàbí tó ń wá ọ̀nà láti ba ayé ẹlòmíràn jẹ́, ṣùgbọ́n tí àwọn ènìyàn rí i pé ète búburú rẹ̀ yóò padà tì í lójú tàbí pa á lára.
It means a person who tries to sabotage or destroy someone else's success/business will end up helping it grow instead — or destroying themselves in the process.
#yorubaculture #viralreelsシ #fypシ゚viralシ #OurHeritage #area1tv

0 likes · 0 comments · 0 shares