Post by Sunday Ajayi (@Areafather)
Ẹni tí kò bá lè kó tìjú kúrò lójú láti ṣe iṣẹ́ kára (ṣe bí aláàrú) níbi tí wọn kò mọ̀ ọ́n sí, kò ní le rìn gẹ́gẹ́ bí ọlọ́rọ̀ tàbí èèyàn ńlá (Adégboro) láàárín ìlú ní ọjọ́ iwájú.
Ti o ko ba le tẹ orí ba láti ṣe iṣẹ́ àṣekára lónìí, o kò ní le gbé orí rẹ sókè gẹ́gẹ́ bí ọlọ́lá lọ́la. Ìyà (iṣẹ́) ní ń fojuure sọni d'ọlọ́lá.
(Start with what you have, no matter how small, in order to become prosperous.)
#OurHeritage #oweyoruba #yorubaculture #highlight #viralreelsシ #area1tv #reelsviralシ

0 likes · 0 comments · 0 shares
Comments
Dada Ogbegun: Oro le so omo iya.